Samuẹli Keji 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó wí fún Uraya pé, “Máa lọ sí ilé rẹ kí o sì sinmi fún ìgbà díẹ̀.” Uraya kúrò lọ́dọ̀ ọba, Dafidi sì di ẹ̀bùn ranṣẹ sí i.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:4-11