Samuẹli Keji 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Uraya kò lọ sí ilé rẹ̀, ó sùn sí ẹnu ọ̀nà ààfin pẹlu àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba tí ń ṣọ́ ààfin.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:1-19