Samuẹli Keji 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Àwọn ọ̀tá wa lágbára jù wá lọ, wọ́n sì jáde láti inú ìlú wọn láti bá wa jà ninu pápá, ṣugbọn a lé wọn pada títí dé ẹnubodè ìlú wọn.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:20-27