Samuẹli Keji 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tafàtafà bẹ̀rẹ̀ sí ta ọfà sí wa láti orí ògiri wọn, wọ́n sì pa ninu àwọn ọ̀gágun rẹ, wọ́n pa Uraya náà pẹlu.”

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:22-27