Samuẹli Keji 11:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Oníṣẹ́ náà bá tọ Dafidi lọ, ó sì ròyìn fún un gẹ́gẹ́ bí Joabu ti rán an pé kí ó sọ.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:17-23