Samuẹli Keji 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Múra gírí, jẹ́ kí á fi gbogbo agbára wa jà fún àwọn eniyan wa ati fún ìlú Ọlọrun wa. Kí OLUWA wa ṣe èyí tí ó dára lójú rẹ̀.”

Samuẹli Keji 10

Samuẹli Keji 10:11-15