Samuẹli Keji 10:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu wí fún un pé, “Bí o bá rí i pé àwọn ará Siria fẹ́ ṣẹgun mi, wá ràn mí lọ́wọ́. Bí èmi náà bá sì rí i pé àwọn ará Amoni fẹ́ ṣẹgun rẹ, n óo wá ràn ọ́ lọ́wọ́.

Samuẹli Keji 10

Samuẹli Keji 10:6-13