Samuẹli Keji 10:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tẹ̀síwájú láti gbógun ti àwọn ará Siria, àwọn ará Siria sì sá.

Samuẹli Keji 10

Samuẹli Keji 10:12-19