Peteru Keji 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn tí ó rí ìbáwí fún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. Ẹranko tí kò lè fọhùn sọ̀rọ̀ bí eniyan, ó dí wolii náà lọ́wọ́ ninu ìwà aṣiwèrè rẹ̀.

Peteru Keji 2

Peteru Keji 2:6-22