Peteru Keji 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi ọ̀nà títọ́ sílẹ̀, wọ́n ń ṣe ránun-rànun kiri. Wọ́n tẹ̀lé ọ̀nà Balaamu ọmọ Beori, tí ó fẹ́ràn èrè aiṣododo.

Peteru Keji 2

Peteru Keji 2:11-22