Peteru Keji 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dàbí ìsun omi tí ó ti gbẹ, ati ìkùukùu tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́ kiri. Ọlọrun ti pèsè ọ̀gbun tí ó ṣókùnkùn biribiri fún wọn.

Peteru Keji 2

Peteru Keji 2:10-22