Èso Mandirake ń tú òórùn dídùn jáde,ẹnu ọ̀nà wa kún fún oríṣìíríṣìí èso tí ó wuni,tí mo ti pèsè wọn dè ọ́, olùfẹ́ mi,ati tuntun ati èyí tó ti pẹ́ nílé.