Kí á lọ sinu ọgbà àjàrà láàárọ̀ kutukutu,kí á wò ó bóyá àjàrà ti ń rúwé,bóyá ó ti ń tanná;kí á wò ó bóyá igi Pomegiranate ti ń tanná,níbẹ̀ ni n óo ti fi ìfẹ́ mi fún ọ.