sibẹ, ọ̀kan ṣoṣo ni àdàbà mi, olùfẹ́ mi tí ó péye.Ọmọlójú ìyá rẹ̀,ẹni tí kò ní àbààwọ́n lójú ẹni tí ó bí i.Àwọn iranṣẹbinrin ń pe ìyá rẹ̀ ní olóríire.Àwọn ayaba ati àwọn obinrin mìíràn ní ààfin sì ń yìn ín.