Àwọn ayaba ìbáà tó ọgọta,kí àwọn obinrin mìíràn sì tó ọgọrin,kí àwọn iranṣẹbinrin sì pọ̀, kí wọn má lóǹkà,