Ta ni ń yọ bọ̀ bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ yìí,tí ó mọ́ bí ọjọ́,tí ó lẹ́wà bí òṣùpá.Tí ó sì bani lẹ́rù,bí àwọn ọmọ ogun tí wọn dira ogun?