Mo lọ sinu ọgbà igi eléso,mo lọ wo ẹ̀ka igi tútù ní àfonífojì,pé bóyá àwọn àjàrà ti rúwé,ati pé bóyá àwọn igi èso pomegiranate tí ń tanná.