Orin Solomoni 6:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Níbo ni olùfẹ́ rẹ lọ,ìwọ, arẹwà jùlọ láàrin àwọn obinrin?Níbo ni olùfẹ́ rẹ yà sí,kí á lè bá ọ wá a?

2. Olùfẹ́ mi ti lọ sinu ọgbà rẹ̀,níbi ebè igi turari,ó da ẹran rẹ̀ lọ sinu ọgbà,ó lọ já òdòdó lílì.

Orin Solomoni 6