Orin Solomoni 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsẹ̀ rẹ ti dára tó ninu bàtà,ìwọ, ọmọ aládé.Itan rẹ dàbí ohun ọ̀ṣọ́,tí ọlọ́gbọ́n oníṣọ̀nà ṣe.

Orin Solomoni 7

Orin Solomoni 7:1-6