Ẹsẹ̀ rẹ̀ dàbí òpó alabasitatí a gbé ka orí ìtẹ́lẹ̀ wúrà.Ìrísí rẹ̀ dàbí òkè Lẹbanoni, ó rí gbọ̀ngbọ̀nràn bí igi Kedari.