Eyín rẹ dàbí ọ̀wọ́ aguntan tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ gé irun wọn,tí wọn wá fọ̀;gbogbo wọn gún régé,Kò sí ọ̀kan kan tí ó yọ ninu wọn.