Orin Solomoni 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ètè rẹ dàbí òwú pupa;ẹnu rẹ fanimọ́ra,ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ ń dán bí ìlàjì èso Pomegiranate,lábẹ́ ìbòjú rẹ.

Orin Solomoni 4

Orin Solomoni 4:1-11