Orin Dafidi 97:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA jọba, kí ayé ó yọ̀;jẹ́ kí inú ogunlọ́gọ̀ erékùṣù ó dùn.

2. Ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri ni ó yí i ká;òdodo ati ẹ̀tọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 97