Orin Dafidi 98:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ orin titun sí OLUWA,nítorí tí ó ti ṣe ohun ìyanu;agbára ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ati apá mímọ́ rẹ̀ ni ó fi ṣẹgun.

Orin Dafidi 98

Orin Dafidi 98:1-8