Orin Dafidi 97:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri ni ó yí i ká;òdodo ati ẹ̀tọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 97

Orin Dafidi 97:1-11