Orin Dafidi 91:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Nítorí yóo pàṣẹ fún àwọn angẹli rẹ̀, nítorí rẹ,pé kí wọ́n máa pa ọ́ mọ́ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.

12. Wọ́n óo fi ọwọ́ wọn gbé ọ sókè,kí o má baà fi ẹsẹ̀ gbún òkúta.

13. O óo rìn kọjá lórí kinniun ati paramọ́lẹ̀;ẹgbọ̀rọ̀ kinniun ati ejò ńlá ni o óo fi ẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́lẹ̀.

Orin Dafidi 91