Orin Dafidi 92:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dára kí eniyan máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, OLUWA;kí ó sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá Ògo;

Orin Dafidi 92

Orin Dafidi 92:1-2