Orin Dafidi 90:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojurere OLUWA Ọlọrun wa wà lára wa,fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀,jẹ́ kí iṣẹ́ ọwọ́ wa fi ìdí múlẹ̀.

Orin Dafidi 90

Orin Dafidi 90:16-17