Orin Dafidi 89:50-51 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA, ranti bí èmi, iranṣẹ rẹ, ti di ẹni yẹ̀yẹ́;ati bí mo ti ń farada ẹ̀gàn àwọn eniyan, OLUWA