Orin Dafidi 89:50 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ranti bí èmi, iranṣẹ rẹ, ti di ẹni yẹ̀yẹ́;ati bí mo ti ń farada ẹ̀gàn àwọn eniyan,

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:48-51