O ti mú kí ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi ati àwọn alábàárìn mi kọ̀ mí sílẹ̀;òkùnkùn nìkan ni ó yí mi ká níbi gbogbo.