Orin Dafidi 89:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, n óo máa kọrin ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ títí lae;n óo máa fi ẹnu mi kéde òtítọ́ rẹ láti ìran dé ìran.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:1-11