Orin Dafidi 89:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, a ti fi ìdí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ múlẹ̀ títí lae;o sì ti fi ìdí òtítọ́ rẹ múlẹ̀ bí ojú ọ̀run.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:1-6