Orin Dafidi 86:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ìwọ, OLUWA, ni Ọlọrun aláàánú ati olóore;o kì í tètè bínú, o sì kún fún ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:14-17