Orin Dafidi 86:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kọjú sí mi, kí o sì ṣàánú mi;fún èmi iranṣẹ rẹ ní agbára rẹ;kí o sì gba èmi ọmọ iranṣẹbinrin rẹ là.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:8-17