Orin Dafidi 86:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, àwọn agbéraga dìde sí mi;ẹgbẹ́ àwọn ìkà, aláìláàánú kan ń lépa ẹ̀mí mi;wọn kò sì bìkítà fún ọ.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:8-17