Orin Dafidi 79:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun, àwọn orílẹ̀-èdè abọ̀rìṣà ti wọ inú ilẹ̀ ìní rẹ;wọ́n ti ba ilé mímọ́ rẹ jẹ́;wọ́n sì ti sọ Jerusalẹmu di ahoro.

2. Wọ́n ti fi òkú àwọn iranṣẹ rẹfún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run jẹ;wọ́n sì ti sọ òkú àwọn eniyan mímọ́ rẹ di ìjẹfún àwọn ẹranko ìgbẹ́.

Orin Dafidi 79