Orin Dafidi 79:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, àwọn orílẹ̀-èdè abọ̀rìṣà ti wọ inú ilẹ̀ ìní rẹ;wọ́n ti ba ilé mímọ́ rẹ jẹ́;wọ́n sì ti sọ Jerusalẹmu di ahoro.

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:1-2