Orin Dafidi 79:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ti fi òkú àwọn iranṣẹ rẹfún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run jẹ;wọ́n sì ti sọ òkú àwọn eniyan mímọ́ rẹ di ìjẹfún àwọn ẹranko ìgbẹ́.

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:1-7