Orin Dafidi 75:9-10 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Ṣugbọn èmi óo máa yọ̀ títí lae,n óo kọ orin ìyìn sí Ọlọrun Jakọbu.

10. Ọlọrun yóo gba gbogbo agbára ọwọ́ àwọn eniyan burúkú kúrò;ṣugbọn yóo fi agbára kún agbára fún àwọn olódodo.

Orin Dafidi 75