Orin Dafidi 74:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Má gbàgbé ariwo àwọn ọ̀tá rẹ;àní, igbe àwọn tí ó gbógun tì ọ́, tí wọn ń ké láìdá ẹnu dúró.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:21-23