Orin Dafidi 75:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn èmi óo máa yọ̀ títí lae,n óo kọ orin ìyìn sí Ọlọrun Jakọbu.

Orin Dafidi 75

Orin Dafidi 75:6-10