Orin Dafidi 73:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ nígbà gbogbo ni mo wà lọ́dọ̀ rẹ;o sì di ọwọ́ ọ̀tún mi mú.

Orin Dafidi 73

Orin Dafidi 73:13-26