Orin Dafidi 65:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ò ń ṣìkẹ́ ayé, o sì ń bomi rin ín,o mú kí ilẹ̀ jí kí ó sì lẹ́tù lójú;o mú kí omi kún inú odò ìwọ Ọlọrun,o mú kí ọkà hù lórí ilẹ̀;nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni o ṣe ṣètò rẹ̀.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:2-13