Orin Dafidi 65:10 BIBELI MIMỌ (BM)

O bomi rin poro oko rẹ̀ lọpọlọpọ,o ṣètò àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀;o rọ òjò tó mú kí ilẹ̀ rọ̀,o sì mú kí ohun ọ̀gbìn rẹ̀ dàgbà.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:5-13