Orin Dafidi 65:11 BIBELI MIMỌ (BM)

O mú kí ìkórè oko pọ̀ yanturu ní òpin ọdún;gbogbo ipa ọ̀nà rẹ sì kún fún ọpọlọpọ ìkórè oko.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:4-13