Orin Dafidi 65:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ń gbé ìpẹ̀kun ayé sì ń bẹ̀rùnítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ;o mú kí àwọn eniyan, láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀, hó ìhó ayọ̀.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:7-9