Òmùgọ̀ sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé,“Kò sí Ọlọrun.”Wọ́n bàjẹ́, ohun ìríra ni wọ́n ń ṣe,kò sì sí ẹnìkan ninu wọn tí ń ṣe rere.