Orin Dafidi 52:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae,nítorí ohun tí o ṣe,n óo máa kéde orúkọ rẹ níwájú àwọn olùfọkànsìn rẹ,nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.

Orin Dafidi 52

Orin Dafidi 52:3-9