Orin Dafidi 52:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn èmi dàbí igi olifi tútùtí ń dàgbà ninu ilé OLUWA,mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọrun tí kì í yẹ̀, lae ati laelae.

Orin Dafidi 52

Orin Dafidi 52:1-9